
Matthias Fiedler
Èrò Fífi Dúkìá Àfojúrí: A Ti Mú Kí Ṣíṣe Alárinà DuL

Èrò Fífi Dúkìá Àfojúrí: A Ti Mú Kí Ṣíṣe Alárinà DuL
Ìwé yìí nṣàlàyé èrò kan tí ó jẹ́ àrà-ọ̀tọ̀ nípa ojú òpó àgbáyé fún fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn (aapu) pẹ̀lú ìṣirò àfojúsùn ọjà títà tí ó jọjú (Biliọnu Dọla), tí a gbé wọ inú sọfwea ti ilé iṣẹ́ dúkìá àfojúrí títí dórí àyẹ̀wò dúkìá àfojúrí (ọjà títà tí ó lè tó Tiriliọnu Dọla).
Èyí ntúmọ̀ sí pé dúkìá àfojúrí fún gbígbé àti ìdókòwò, bóyá ti àdáni àbí àyálò, ni a lè ṣe alárinà fún ní ọ̀nà tí ó múná dóko tí kò sì fi àkókò ṣòfò. Òun ni ọjọ́ ọ̀la ṣíṣe alárinà dúkìá àfojúrí tí ó jẹ́ ọ̀tun tí ó sì dára fún gbogbo àwọn aṣojú fún dúkìá àfojúrí àti àwọn tí ó ní dúkìá. Ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ pé gbogbo orílẹ̀-edè ni fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn ti ní ìtumọ̀ títí dé orílè-èdè kan sí èkejì.
Dípò "gbígbé" dúkìá wá sí ọ̀dọ̀ olùrà àbí ẹni tí ó fẹ́ yá a lò, níwọ̀n ìgbà tí ojú òpó fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn ti wà, àwọn tí ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ olùrà àti olùyálò lè kún ojú òṣùwọ̀n (wá àkọsílẹ̀) kí a sì fi wọ́n wé ara wọn kí a sì fi wọ́n mọ dúkìá tí àwọn aṣojú dúkìá àfojúrí bá gbé jáde.
Author: Matthias Fiedler |
Publisher: Matthias Fiedler |
Publication Date: Feb 28, 2017 |
Number of Pages: 40 pages |
Binding: Paperback or Softback |
ISBN-10: 3947184891 |
ISBN-13: 9783947184897 |